آداب الأكل والشرب

Awọn Ẹkọ ti o nbẹ fun jijẹ ati mimu


محاضرة بلغة اليوربا، وفيها بيان ما يلي:<br /> • الجزء الأول: بيان أن الطعام والشراب من نعم الله التي أنعم بها على خلقه، مع ذكر شيء من الآداب عند بداية الأكل.<br /> • الجزء الثاني: تتمة الحديث حول آداب الأكل والشرب، مع توضيح الأمور التي ينبغي تجنبها أثناء تناول الطعام أو الشراب.
1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ. <br /> 2- Abala yii jẹ itẹsiwaju alaye lori awọn ẹkọ ti o rọ mọ jijẹ ati mimu, ẹkunrẹrẹ alaye si waye lori awọn nkan ti o dara pupọ lati jina si ni asiko ti a ba fẹ jẹ tabi mu.