البحث

عبارات مقترحة:

الولي

كلمة (الولي) في اللغة صفة مشبهة على وزن (فعيل) من الفعل (وَلِيَ)،...

الوتر

كلمة (الوِتر) في اللغة صفة مشبهة باسم الفاعل، ومعناها الفرد،...

السيد

كلمة (السيد) في اللغة صيغة مبالغة من السيادة أو السُّؤْدَد،...

Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam

اليوروبا - Yorùbá

المؤلف Sharafuddeen Gbadebọ Raji ، Hamid Yusuf
القسم دروس ومحاضرات
النوع صوتي
اللغة اليوروبا - Yorùbá
المفردات دواوين السنة
2- Alaye lori awon idajo ti o sopo mo irun Jimoh, ninu won ni: (1) Asiko wo ni irun Jimoh maa n wole. (2) Onka wo ni o ye ki o pe ki a to le ki irun Jimoh. (3) Rakah melo ni Musulumi gbodo ba ki o to le gba pe oun ba irun Jimoh. 3- Alaye lori wipe Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a maa n gbe ohun soke ni ti o ba n se khutuba ti o si maa n se khutuba ni iduro, gbogbo awon nkan wonyi ni o si maa n se okunfa ki khutuba ni ilapa lara awon ti won n gbo o. 4- Oro waye ni apa kerin yi lori Pataki yiyara lo si mosalasi ni ojo Jimoh ati Pataki titeti si Imam ni asiko khutuba, bakannaa ojuse eni ti o ba tete de mosalasi ati eni ti o pe de mosalasi nibi nafila ti a n pe ni "Tahiyyatul-masjid". 5- Oro waye ninu apa karun yi lori awon suura ti Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- maa n ka ninu irun Jimoh ati irun odun mejeeji pelu alaye awon eko ti o wa ninu awon suura naa, oludanileko si tun menu ba awon idajo ti o n be fun awon irun odun mejeeji ti odun ba bo si ojo Jimoh. 6- Alaye wa ninu apa kefa yi lori: (1) Nafila eyin irun Jimoh ati iye onka rakaa re. (2) Iwe fun irun Jimoh, se oranyan ni tabi kiise oranyan. (3) Awon ibeere lori oro Jimoh ati gbogbo ohun ti o ropo mo o pelu idahun lori won.

المرفقات

5

Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -2
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -3
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -4
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -5
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -6