البحث

عبارات مقترحة:

الحق

كلمة (الحَقِّ) في اللغة تعني: الشيءَ الموجود حقيقةً.و(الحَقُّ)...

النصير

كلمة (النصير) في اللغة (فعيل) بمعنى (فاعل) أي الناصر، ومعناه العون...

الجميل

كلمة (الجميل) في اللغة صفة على وزن (فعيل) من الجمال وهو الحُسن،...

Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ

اليوروبا - Yorùbá

المؤلف Abdur Rahman Muhammadul Awwal ، Hamid Yusuf
القسم دروس ومحاضرات
النوع صوتي
اللغة اليوروبا - Yorùbá
المفردات عيسى عليه السلام
1- Itan Iya Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ati itan iya-iya rẹ. 2- Alaye bi wọn se ni oyun Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọna iyanu pẹlu bibi rẹ ni ọna iyanu, ti eleyi ko si sọ di Ọlọhun. 3- Ọrọ nipa isẹ ipepe anọbi Isa pẹlu isẹ ayanu rẹ, ati wipe Iru ẹlẹsin wo ni Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a].

المرفقات

3

Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ -1/3
Anọbi Isa[Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ - 2/3
Anọbi Isa[Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ - 3/3